1 Kọ́ríńtì 7:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Òfin de aya ní gbogbo ìgbà tí ọkọ rẹ̀ bá wà láàyè.+ Àmọ́ tí ọkọ rẹ̀ bá sùn nínú ikú, ó ní òmìnira láti ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ẹni tó bá wù ú, kìkì nínú Olúwa.+
39 Òfin de aya ní gbogbo ìgbà tí ọkọ rẹ̀ bá wà láàyè.+ Àmọ́ tí ọkọ rẹ̀ bá sùn nínú ikú, ó ní òmìnira láti ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ẹni tó bá wù ú, kìkì nínú Olúwa.+