ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 51:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Wò ó! A bí mi ní ẹlẹ́ṣẹ̀,

      Inú ẹ̀ṣẹ̀ sì ni ìyá mi* lóyún mi.+

  • Jòhánù 8:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Jésù dá wọn lóhùn pé: “Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ẹrú ẹ̀ṣẹ̀+ ni gbogbo ẹni tó bá ń dẹ́ṣẹ̀.

  • Róòmù 6:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé tí ẹ bá fi ara yín ṣe ẹrú tó ń ṣègbọràn fún ẹnì kan, ẹrú lẹ jẹ́ fún ẹni tí ẹ̀ ń ṣègbọràn sí,+ ì báà jẹ́ fún ẹ̀ṣẹ̀+ tó ń yọrí sí ikú+ tàbí fún ìgbọràn tó ń yọrí sí òdodo?

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́