Róòmù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nítorí náà, kò sí ẹni* tí a máa pè ní olódodo níwájú rẹ̀ nípasẹ̀ àwọn iṣẹ́ òfin,+ torí òfin ló jẹ́ ká ní ìmọ̀ pípéye nípa ẹ̀ṣẹ̀.+ Hébérù 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Tó bá jẹ́ pé iṣẹ́ àlùfáà+ àwọn ọmọ Léfì lè mú ìjẹ́pípé wá ni (torí ó wà lára Òfin tí a fún àwọn èèyàn), ṣé a tún máa nílò kí àlùfáà míì dìde, ẹni tí a sọ pé ó wà ní ọ̀nà ti Melikisédékì,+ tí kì í ṣe ní ọ̀nà ti Áárónì?
20 Nítorí náà, kò sí ẹni* tí a máa pè ní olódodo níwájú rẹ̀ nípasẹ̀ àwọn iṣẹ́ òfin,+ torí òfin ló jẹ́ ká ní ìmọ̀ pípéye nípa ẹ̀ṣẹ̀.+
11 Tó bá jẹ́ pé iṣẹ́ àlùfáà+ àwọn ọmọ Léfì lè mú ìjẹ́pípé wá ni (torí ó wà lára Òfin tí a fún àwọn èèyàn), ṣé a tún máa nílò kí àlùfáà míì dìde, ẹni tí a sọ pé ó wà ní ọ̀nà ti Melikisédékì,+ tí kì í ṣe ní ọ̀nà ti Áárónì?