Jòhánù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ṣùgbọ́n ó fún gbogbo àwọn tó gbà á ní àṣẹ láti di ọmọ Ọlọ́run,+ torí pé wọ́n ní ìgbàgbọ́ nínú orúkọ rẹ̀.+ Jòhánù 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jésù dáhùn pé: “Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún ọ, tí a kò bá bí ẹnì kan látinú omi+ àti ẹ̀mí,+ kò lè wọ Ìjọba Ọlọ́run.
12 Ṣùgbọ́n ó fún gbogbo àwọn tó gbà á ní àṣẹ láti di ọmọ Ọlọ́run,+ torí pé wọ́n ní ìgbàgbọ́ nínú orúkọ rẹ̀.+
5 Jésù dáhùn pé: “Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún ọ, tí a kò bá bí ẹnì kan látinú omi+ àti ẹ̀mí,+ kò lè wọ Ìjọba Ọlọ́run.