1 Kọ́ríńtì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí àwa ni Ọlọ́run ti ṣí wọn payá fún+ nípasẹ̀ ẹ̀mí rẹ̀,+ nítorí ẹ̀mí ń wá inú ohun gbogbo, títí kan àwọn ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run.+ 1 Kọ́ríńtì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní báyìí, kì í ṣe ẹ̀mí ayé ni àwa gbà, bí kò ṣe ẹ̀mí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ kí a lè mọ àwọn nǹkan tí Ọlọ́run fi ṣe wá lóore. 2 Kọ́ríńtì 1:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ó tún fi èdìdì rẹ̀ sórí wa,+ ó sì ti fún wa ní àmì ìdánilójú ohun tó ń bọ̀,* ìyẹn ẹ̀mí+ tó wà nínú ọkàn wa.
10 Nítorí àwa ni Ọlọ́run ti ṣí wọn payá fún+ nípasẹ̀ ẹ̀mí rẹ̀,+ nítorí ẹ̀mí ń wá inú ohun gbogbo, títí kan àwọn ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run.+
12 Ní báyìí, kì í ṣe ẹ̀mí ayé ni àwa gbà, bí kò ṣe ẹ̀mí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ kí a lè mọ àwọn nǹkan tí Ọlọ́run fi ṣe wá lóore.
22 Ó tún fi èdìdì rẹ̀ sórí wa,+ ó sì ti fún wa ní àmì ìdánilójú ohun tó ń bọ̀,* ìyẹn ẹ̀mí+ tó wà nínú ọkàn wa.