1 Jòhánù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, a ti wá di ọmọ Ọlọ́run,+ àmọ́ a ò tíì fi ohun tí a máa jẹ́ hàn kedere.+ A mọ̀ pé nígbà tí a bá fi í hàn kedere a máa dà bíi rẹ̀, torí a máa rí i bó ṣe rí gẹ́lẹ́.
2 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, a ti wá di ọmọ Ọlọ́run,+ àmọ́ a ò tíì fi ohun tí a máa jẹ́ hàn kedere.+ A mọ̀ pé nígbà tí a bá fi í hàn kedere a máa dà bíi rẹ̀, torí a máa rí i bó ṣe rí gẹ́lẹ́.