Hébérù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ nígbà tó tún mú Àkọ́bí rẹ̀+ wá sí ilẹ̀ ayé tí à ń gbé, ó sọ pé: “Kí gbogbo áńgẹ́lì Ọlọ́run tẹrí ba* fún un.”
6 Àmọ́ nígbà tó tún mú Àkọ́bí rẹ̀+ wá sí ilẹ̀ ayé tí à ń gbé, ó sọ pé: “Kí gbogbo áńgẹ́lì Ọlọ́run tẹrí ba* fún un.”