Hébérù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ọ̀dọ̀ ẹnì kan ni ẹni tó ń sọni di mímọ́ àti àwọn tí à ń sọ di mímọ́+ ti wá,+ torí èyí ni ojú ò ṣe tì í láti pè wọ́n ní arákùnrin,+
11 Torí ọ̀dọ̀ ẹnì kan ni ẹni tó ń sọni di mímọ́ àti àwọn tí à ń sọ di mímọ́+ ti wá,+ torí èyí ni ojú ò ṣe tì í láti pè wọ́n ní arákùnrin,+