Róòmù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nítorí náà, bó ṣe jẹ́ pé àṣemáṣe kan ló yọrí sí ìdálẹ́bi onírúurú èèyàn,+ bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe jẹ́ pé ìwà òdodo kan ló mú ká pe onírúurú èèyàn+ ní olódodo fún ìyè.+ Títù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 kó lè jẹ́ pé lẹ́yìn tí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀ bá ti sọ wá di olódodo,+ a ó lè di ajogún+ ìyè àìnípẹ̀kun tí à ń retí.+
18 Nítorí náà, bó ṣe jẹ́ pé àṣemáṣe kan ló yọrí sí ìdálẹ́bi onírúurú èèyàn,+ bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe jẹ́ pé ìwà òdodo kan ló mú ká pe onírúurú èèyàn+ ní olódodo fún ìyè.+
7 kó lè jẹ́ pé lẹ́yìn tí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀ bá ti sọ wá di olódodo,+ a ó lè di ajogún+ ìyè àìnípẹ̀kun tí à ń retí.+