-
Mátíù 1:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Torí náà, gbogbo ìran náà látọ̀dọ̀ Ábúráhámù dórí Dáfídì jẹ́ ìran mẹ́rìnlá (14); látọ̀dọ̀ Dáfídì di ìgbà tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì, ìran mẹ́rìnlá (14); látìgbà tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì di ìgbà Kristi, ìran mẹ́rìnlá (14).
-