Gálátíà 3:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nítorí náà, Òfin di olùtọ́* wa tó ń sinni lọ sọ́dọ̀ Kristi,+ kí a lè pè wá ní olódodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́.+
24 Nítorí náà, Òfin di olùtọ́* wa tó ń sinni lọ sọ́dọ̀ Kristi,+ kí a lè pè wá ní olódodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́.+