Diutarónómì 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá lé wọn kúrò níwájú rẹ, má sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Òdodo mi ló mú kí Jèhófà mú mi wá gba ilẹ̀ yìí.’+ Torí ìwà burúkú àwọn orílẹ̀-èdè yìí+ ni Jèhófà ṣe máa lé wọn kúrò níwájú rẹ.
4 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá lé wọn kúrò níwájú rẹ, má sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Òdodo mi ló mú kí Jèhófà mú mi wá gba ilẹ̀ yìí.’+ Torí ìwà burúkú àwọn orílẹ̀-èdè yìí+ ni Jèhófà ṣe máa lé wọn kúrò níwájú rẹ.