-
Jeremáyà 31:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “‘Àyàfi bí a bá lè díwọ̀n ọ̀run lókè, tí a sì lè wá ìpìlẹ̀ ayé kàn nísàlẹ̀, ni màá tó kọ gbogbo àtọmọdọ́mọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ torí àwọn ohun tí wọ́n ti ṣe,’ ni Jèhófà wí.”+
-