2 Kọ́ríńtì 3:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́ èrò inú wọn ò ṣiṣẹ́ dáadáa mọ́.+ Nítorí títí di òní yìí, a kò ká ìbòjú yẹn kúrò tí a bá ń ka májẹ̀mú láéláé,+ torí ipasẹ̀ Kristi nìkan la fi ń mú un kúrò.+ 15 Kódà, títí di òní, nígbàkigbà tí wọ́n bá ń ka ìwé Mósè,+ ìbòjú máa ń bo ọkàn wọn.+
14 Àmọ́ èrò inú wọn ò ṣiṣẹ́ dáadáa mọ́.+ Nítorí títí di òní yìí, a kò ká ìbòjú yẹn kúrò tí a bá ń ka májẹ̀mú láéláé,+ torí ipasẹ̀ Kristi nìkan la fi ń mú un kúrò.+ 15 Kódà, títí di òní, nígbàkigbà tí wọ́n bá ń ka ìwé Mósè,+ ìbòjú máa ń bo ọkàn wọn.+