-
Sáàmù 14:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ká ní ìgbàlà Ísírẹ́lì lè wá láti Síónì+ ni!
Nígbà tí Jèhófà bá kó àwọn èèyàn rẹ̀ tó wà lóko ẹrú pa dà,
Kí inú Jékọ́bù dùn, kí Ísírẹ́lì sì yọ̀.
-