-
Àìsáyà 59:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Olùtúnrà+ máa wá sí Síónì,+
Sọ́dọ̀ àwọn ti Jékọ́bù, àwọn tó yí pa dà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀,”+ ni Jèhófà wí.
21 “Ní tèmi, májẹ̀mú tí mo bá wọn dá nìyí,”+ ni Jèhófà wí. “Ẹ̀mí mi tó wà lára rẹ àti àwọn ọ̀rọ̀ mi tí mo fi sí ẹnu rẹ kò ní kúrò ní ẹnu rẹ, ní ẹnu àwọn ọmọ* rẹ tàbí ní ẹnu àwọn ọmọ ọmọ rẹ,”* ni Jèhófà wí, “láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.”
-