Éfésù 4:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Torí náà, ẹ máa di tuntun nínú agbára tó ń darí ìrònú yín,*+ 24 kí ẹ sì gbé ìwà tuntun wọ̀,+ èyí tí a dá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run nínú òdodo tòótọ́ àti ìdúróṣinṣin.
23 Torí náà, ẹ máa di tuntun nínú agbára tó ń darí ìrònú yín,*+ 24 kí ẹ sì gbé ìwà tuntun wọ̀,+ èyí tí a dá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run nínú òdodo tòótọ́ àti ìdúróṣinṣin.