Róòmù 11:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí náà, ronú nípa inú rere Ọlọ́run+ àti bó ṣe ń fìyà jẹni. Ìyà wà fún àwọn tó ṣubú,+ àmọ́ inú rere Ọlọ́run wà fún ìwọ, kìkì bí o bá dúró nínú inú rere rẹ̀; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, a ó ṣẹ́ ìwọ náà kúrò. Éfésù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ipasẹ̀ ìràpadà tó fi ẹ̀jẹ̀ ọmọ rẹ̀ san ni a fi rí ìtúsílẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni, ìdáríjì àwọn àṣemáṣe wa,+ nítorí ọlá inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀.
22 Nítorí náà, ronú nípa inú rere Ọlọ́run+ àti bó ṣe ń fìyà jẹni. Ìyà wà fún àwọn tó ṣubú,+ àmọ́ inú rere Ọlọ́run wà fún ìwọ, kìkì bí o bá dúró nínú inú rere rẹ̀; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, a ó ṣẹ́ ìwọ náà kúrò.
7 Ipasẹ̀ ìràpadà tó fi ẹ̀jẹ̀ ọmọ rẹ̀ san ni a fi rí ìtúsílẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni, ìdáríjì àwọn àṣemáṣe wa,+ nítorí ọlá inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀.