1 Pétérù 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ máa ṣe ara yín lálejò láìráhùn.+ 3 Jòhánù 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, ó di dandan pé ká fi aájò àlejò hàn sí àwọn ẹni bẹ́ẹ̀,+ ká lè jọ máa ṣiṣẹ́ nínú òtítọ́.+