Jóòbù 37:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí náà, ó yẹ kí àwọn èèyàn bẹ̀rù rẹ̀.+ Torí kì í ṣe ojúure sí ẹnikẹ́ni tó gbọ́n lójú ara rẹ̀.”*+ Òwe 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara rẹ.+ Bẹ̀rù Jèhófà kí o sì yẹra fún ibi.
24 Torí náà, ó yẹ kí àwọn èèyàn bẹ̀rù rẹ̀.+ Torí kì í ṣe ojúure sí ẹnikẹ́ni tó gbọ́n lójú ara rẹ̀.”*+