Kólósè 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́, yàtọ̀ sí gbogbo àwọn nǹkan yìí, ẹ fi ìfẹ́ wọ ara yín láṣọ,+ nítorí ó jẹ́ ìdè ìrẹ́pọ̀ pípé.+ 1 Tímótì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní tòótọ́, ìdí tí mo fi ń sọ ìtọ́ni* yìí jẹ́ nítorí ìfẹ́+ látinú ọkàn tó mọ́, látinú ẹ̀rí ọkàn rere àti látinú ìgbàgbọ́+ tí kò ní àgàbàgebè. 1 Jòhánù 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ̀yin ẹni ọ̀wọ́n, tó bá jẹ́ pé bí Ọlọ́run ṣe nífẹ̀ẹ́ wa nìyí, àwa náà gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ ara wa.+
14 Àmọ́, yàtọ̀ sí gbogbo àwọn nǹkan yìí, ẹ fi ìfẹ́ wọ ara yín láṣọ,+ nítorí ó jẹ́ ìdè ìrẹ́pọ̀ pípé.+
5 Ní tòótọ́, ìdí tí mo fi ń sọ ìtọ́ni* yìí jẹ́ nítorí ìfẹ́+ látinú ọkàn tó mọ́, látinú ẹ̀rí ọkàn rere àti látinú ìgbàgbọ́+ tí kò ní àgàbàgebè.