Róòmù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ o, ó yẹ kí àwa tí a lókun máa ru àìlera àwọn tí kò lókun,+ ká má sì máa ṣe ohun tó wù wá.+ 1 Tẹsalóníkà 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́sẹ̀ kan náà, ẹ̀yin ará, à ń rọ̀ yín pé kí ẹ máa kìlọ̀ fún àwọn tó ń ṣe ségesège,*+ ẹ máa sọ̀rọ̀ ìtùnú fún àwọn tó sorí kọ́,* ẹ máa ran àwọn aláìlera lọ́wọ́, ẹ máa mú sùúrù fún gbogbo èèyàn.+
14 Lẹ́sẹ̀ kan náà, ẹ̀yin ará, à ń rọ̀ yín pé kí ẹ máa kìlọ̀ fún àwọn tó ń ṣe ségesège,*+ ẹ máa sọ̀rọ̀ ìtùnú fún àwọn tó sorí kọ́,* ẹ máa ran àwọn aláìlera lọ́wọ́, ẹ máa mú sùúrù fún gbogbo èèyàn.+