Ìṣe 10:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Bákan náà, ó pàṣẹ fún wa pé ká wàásù fún àwọn èèyàn ká sì jẹ́rìí kúnnákúnná+ pé ẹni yìí ni Ọlọ́run pàṣẹ pé kí ó jẹ́ onídàájọ́ alààyè àti òkú.+ 2 Kọ́ríńtì 5:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí gbogbo wa ló máa fara hàn* níwájú ìjókòó ìdájọ́ Kristi, kí kálukú lè gba èrè àwọn ohun tó ṣe nígbà tó wà nínú ara, ì báà jẹ́ rere tàbí búburú.*+
42 Bákan náà, ó pàṣẹ fún wa pé ká wàásù fún àwọn èèyàn ká sì jẹ́rìí kúnnákúnná+ pé ẹni yìí ni Ọlọ́run pàṣẹ pé kí ó jẹ́ onídàájọ́ alààyè àti òkú.+
10 Nítorí gbogbo wa ló máa fara hàn* níwájú ìjókòó ìdájọ́ Kristi, kí kálukú lè gba èrè àwọn ohun tó ṣe nígbà tó wà nínú ara, ì báà jẹ́ rere tàbí búburú.*+