Ìṣe 20:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Síbẹ̀, mi ò ka ẹ̀mí* mi sí ohun tó ṣe pàtàkì* sí mi, tí mo bá ṣáà ti lè parí eré ìje mi+ àti iṣẹ́ òjíṣẹ́ tí mo gbà lọ́wọ́ Jésù Olúwa, láti jẹ́rìí kúnnákúnná sí ìhìn rere nípa inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run.
24 Síbẹ̀, mi ò ka ẹ̀mí* mi sí ohun tó ṣe pàtàkì* sí mi, tí mo bá ṣáà ti lè parí eré ìje mi+ àti iṣẹ́ òjíṣẹ́ tí mo gbà lọ́wọ́ Jésù Olúwa, láti jẹ́rìí kúnnákúnná sí ìhìn rere nípa inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run.