1 Kọ́ríńtì 14:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Nítorí Ọlọ́run kì í ṣe Ọlọ́run rúdurùdu, bí kò ṣe ti àlàáfíà.+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe rí nínú gbogbo ìjọ àwọn ẹni mímọ́, Fílípì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ohun tí ẹ kọ́, tí ẹ tẹ́wọ́ gbà, tí ẹ gbọ́, tí ẹ sì rí lọ́dọ̀ mi, ẹ máa fi wọ́n sílò,+ Ọlọ́run àlàáfíà yóò sì wà pẹ̀lú yín.
33 Nítorí Ọlọ́run kì í ṣe Ọlọ́run rúdurùdu, bí kò ṣe ti àlàáfíà.+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe rí nínú gbogbo ìjọ àwọn ẹni mímọ́,
9 Àwọn ohun tí ẹ kọ́, tí ẹ tẹ́wọ́ gbà, tí ẹ gbọ́, tí ẹ sì rí lọ́dọ̀ mi, ẹ máa fi wọ́n sílò,+ Ọlọ́run àlàáfíà yóò sì wà pẹ̀lú yín.