-
Róòmù 16:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ẹ kí Andironíkọ́sì àti Júníásì, àwọn ìbátan mi,+ tí a jọ ṣẹ̀wọ̀n, àwọn tí àwọn àpọ́sítélì mọ̀ dáadáa, tí wọ́n sì ti pẹ́ jù mí lọ nínú Kristi.
-