-
Róòmù 3:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 A mọ̀ pé gbogbo nǹkan tí Òfin sọ ló wà fún àwọn tó wà lábẹ́ Òfin, kí a lè pa gbogbo èèyàn lẹ́nu mọ́, kí gbogbo ayé sì lè yẹ fún ìyà lọ́dọ̀ Ọlọ́run.+
-