Jòhánù 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí Baba kì í ṣèdájọ́ ẹnikẹ́ni, àmọ́ ó ti fi gbogbo ìdájọ́ lé Ọmọ lọ́wọ́,+ Ìṣe 10:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Bákan náà, ó pàṣẹ fún wa pé ká wàásù fún àwọn èèyàn ká sì jẹ́rìí kúnnákúnná+ pé ẹni yìí ni Ọlọ́run pàṣẹ pé kí ó jẹ́ onídàájọ́ alààyè àti òkú.+ 1 Pétérù 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn yìí máa jíhìn fún ẹni tó ti ṣe tán láti ṣèdájọ́ àwọn tó wà láàyè àtàwọn tó ti kú.+
42 Bákan náà, ó pàṣẹ fún wa pé ká wàásù fún àwọn èèyàn ká sì jẹ́rìí kúnnákúnná+ pé ẹni yìí ni Ọlọ́run pàṣẹ pé kí ó jẹ́ onídàájọ́ alààyè àti òkú.+
5 Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn yìí máa jíhìn fún ẹni tó ti ṣe tán láti ṣèdájọ́ àwọn tó wà láàyè àtàwọn tó ti kú.+