Jòhánù 8:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Wọ́n dá a lóhùn pé: “Ábúráhámù ni bàbá wa.” Jésù sọ fún wọn pé: “Tó bá jẹ́ pé ọmọ Ábúráhámù ni yín,+ àwọn iṣẹ́ Ábúráhámù lẹ̀ bá máa ṣe. Ìfihàn 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 ‘Mo mọ ìpọ́njú àti ipò òṣì rẹ—àmọ́ ọlọ́rọ̀ ni ọ́+—àti ọ̀rọ̀ òdì àwọn tó ń pe ara wọn ní Júù, síbẹ̀ tí wọn kì í ṣe Júù, àmọ́ sínágọ́gù Sátánì ni wọ́n.+
39 Wọ́n dá a lóhùn pé: “Ábúráhámù ni bàbá wa.” Jésù sọ fún wọn pé: “Tó bá jẹ́ pé ọmọ Ábúráhámù ni yín,+ àwọn iṣẹ́ Ábúráhámù lẹ̀ bá máa ṣe.
9 ‘Mo mọ ìpọ́njú àti ipò òṣì rẹ—àmọ́ ọlọ́rọ̀ ni ọ́+—àti ọ̀rọ̀ òdì àwọn tó ń pe ara wọn ní Júù, síbẹ̀ tí wọn kì í ṣe Júù, àmọ́ sínágọ́gù Sátánì ni wọ́n.+