1 Kọ́ríńtì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 nígbà tí Ọlọ́run ń dá àwọn tó wà lóde lẹ́jọ́?+ “Ẹ mú ẹni burúkú náà kúrò láàárín yín.”+ 2 Jòhánù 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bí ẹnikẹ́ni bá wá sọ́dọ̀ yín, tí kò sì mú ẹ̀kọ́ yìí wá, ẹ má gbà á sílé,+ ẹ má sì kí i.