1 Tímótì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Híméníọ́sì+ àti Alẹkisáńdà wà lára irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀, mo sì ti fi wọ́n lé Sátánì lọ́wọ́,+ kí a lè fi ìbáwí kọ́ wọn lẹ́kọ̀ọ́ pé kí wọ́n má sọ̀rọ̀ òdì mọ́.
20 Híméníọ́sì+ àti Alẹkisáńdà wà lára irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀, mo sì ti fi wọ́n lé Sátánì lọ́wọ́,+ kí a lè fi ìbáwí kọ́ wọn lẹ́kọ̀ọ́ pé kí wọ́n má sọ̀rọ̀ òdì mọ́.