Mátíù 5:39, 40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé: Ẹ má ṣe ta ko ẹni burúkú, àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá gbá yín ní etí* ọ̀tún, ẹ yí èkejì sí i.+ 40 Tí ẹnì kan bá fẹ́ mú ọ lọ sí ilé ẹjọ́, kó sì gba aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ, jẹ́ kó gba aṣọ àwọ̀lékè rẹ pẹ̀lú;+
39 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé: Ẹ má ṣe ta ko ẹni burúkú, àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá gbá yín ní etí* ọ̀tún, ẹ yí èkejì sí i.+ 40 Tí ẹnì kan bá fẹ́ mú ọ lọ sí ilé ẹjọ́, kó sì gba aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ, jẹ́ kó gba aṣọ àwọ̀lékè rẹ pẹ̀lú;+