Róòmù 16:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Gáyọ́sì,+ tó gba èmi àti gbogbo ìjọ lálejò, kí yín. Érásítù, ẹni tó ń bójú tó ìṣúra ìlú,* kí yín, Kúátọ́sì, arákùnrin rẹ̀ náà kí yín.
23 Gáyọ́sì,+ tó gba èmi àti gbogbo ìjọ lálejò, kí yín. Érásítù, ẹni tó ń bójú tó ìṣúra ìlú,* kí yín, Kúátọ́sì, arákùnrin rẹ̀ náà kí yín.