Jẹ́nẹ́sísì 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ìdí nìyẹn tí ọkùnrin á ṣe fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́* ìyàwó rẹ̀, wọ́n á sì di ara kan.+ Mátíù 19:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó dá wọn lóhùn pé: “Ṣé ẹ ò kà á pé ẹni tó dá wọn ní ìbẹ̀rẹ̀ dá wọn ní akọ àti abo,+ 5 ó sì sọ pé, ‘Torí èyí, ọkùnrin á fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́ ìyàwó rẹ̀, àwọn méjèèjì á sì di ara kan’?+
24 Ìdí nìyẹn tí ọkùnrin á ṣe fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́* ìyàwó rẹ̀, wọ́n á sì di ara kan.+
4 Ó dá wọn lóhùn pé: “Ṣé ẹ ò kà á pé ẹni tó dá wọn ní ìbẹ̀rẹ̀ dá wọn ní akọ àti abo,+ 5 ó sì sọ pé, ‘Torí èyí, ọkùnrin á fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́ ìyàwó rẹ̀, àwọn méjèèjì á sì di ara kan’?+