-
1 Kọ́ríńtì 16:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ní báyìí, mo rọ̀ yín, ẹ̀yin ará: Ẹ mọ̀ pé agbo ilé Sítéfánásì ni àkọ́so Ákáyà àti pé wọ́n ti yọ̀ǹda ara wọn láti máa ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn ẹni mímọ́.
-