-
Róòmù 1:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Torí náà, Ọlọ́run fi wọ́n sílẹ̀ fún ìwà àìmọ́, kí wọ́n lè máa ṣe ìfẹ́ ọkàn wọn, kí wọ́n sì tàbùkù sí ẹran ara wọn.