Hébérù 12:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹ máa lépa àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn+ àti ìsọdimímọ́,*+ tó jẹ́ pé láìsí i, èèyàn kankan ò lè rí Olúwa.
14 Ẹ máa lépa àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn+ àti ìsọdimímọ́,*+ tó jẹ́ pé láìsí i, èèyàn kankan ò lè rí Olúwa.