Ìṣe 21:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í yin Ọlọ́run lógo, àmọ́ wọ́n sọ fún un pé: “Arákùnrin, wo bí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn onígbàgbọ́ tó wà láàárín àwọn Júù ṣe pọ̀ tó, gbogbo wọn ló sì ní ìtara fún Òfin.+
20 Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í yin Ọlọ́run lógo, àmọ́ wọ́n sọ fún un pé: “Arákùnrin, wo bí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn onígbàgbọ́ tó wà láàárín àwọn Júù ṣe pọ̀ tó, gbogbo wọn ló sì ní ìtara fún Òfin.+