Gálátíà 6:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí ìdádọ̀dọ́* tàbí àìdádọ̀dọ́* kọ́ ló ṣe pàtàkì,+ ẹ̀dá tuntun ló ṣe pàtàkì.+ Kólósè 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 níbi tí kò ti sí Gíríìkì tàbí Júù, ìdádọ̀dọ́* tàbí àìdádọ̀dọ́,* àjèjì, Sítíánì,* ẹrú tàbí òmìnira; àmọ́ Kristi ni ohun gbogbo, ó sì wà nínú ohun gbogbo.+
11 níbi tí kò ti sí Gíríìkì tàbí Júù, ìdádọ̀dọ́* tàbí àìdádọ̀dọ́,* àjèjì, Sítíánì,* ẹrú tàbí òmìnira; àmọ́ Kristi ni ohun gbogbo, ó sì wà nínú ohun gbogbo.+