-
Róòmù 14:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àmọ́ tó bá ń ṣiyèméjì, a ti dá a lẹ́bi tó bá jẹ ẹ́, nítorí kò jẹ ẹ́ pẹ̀lú ìgbàgbọ́. Ní tòótọ́, gbogbo ohun tí kò bá ti bá ìgbàgbọ́ mu jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.
-