Róòmù 14:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí Ìjọba Ọlọ́run kò ní nǹkan kan ṣe pẹ̀lú jíjẹ àti mímu,+ àmọ́ ó ní í ṣe pẹ̀lú òdodo àti àlàáfíà àti ayọ̀ pẹ̀lú ẹ̀mí mímọ́.
17 Nítorí Ìjọba Ọlọ́run kò ní nǹkan kan ṣe pẹ̀lú jíjẹ àti mímu,+ àmọ́ ó ní í ṣe pẹ̀lú òdodo àti àlàáfíà àti ayọ̀ pẹ̀lú ẹ̀mí mímọ́.