Mátíù 18:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá mú ọ̀kan nínú àwọn ẹni kékeré yìí tó ní ìgbàgbọ́ nínú mi kọsẹ̀, ó sàn ká so ọlọ mọ́ ọn lọ́rùn, irú èyí tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ máa ń yí, ká sì jù ú sínú agbami òkun, kó sì rì.+ Róòmù 14:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí bí o bá ṣẹ arákùnrin rẹ torí oúnjẹ, o ò rìn lọ́nà tó bá ìfẹ́ mu mọ́.+ Má fi oúnjẹ rẹ pa ẹni tí Kristi kú fún run.*+ Róòmù 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ohun tó dáa jù ni pé kéèyàn má jẹ ẹran tàbí kó má mu ọtí tàbí kó má ṣe ohunkóhun tó máa mú arákùnrin rẹ̀ kọsẹ̀.+
6 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá mú ọ̀kan nínú àwọn ẹni kékeré yìí tó ní ìgbàgbọ́ nínú mi kọsẹ̀, ó sàn ká so ọlọ mọ́ ọn lọ́rùn, irú èyí tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ máa ń yí, ká sì jù ú sínú agbami òkun, kó sì rì.+
15 Nítorí bí o bá ṣẹ arákùnrin rẹ torí oúnjẹ, o ò rìn lọ́nà tó bá ìfẹ́ mu mọ́.+ Má fi oúnjẹ rẹ pa ẹni tí Kristi kú fún run.*+
21 Ohun tó dáa jù ni pé kéèyàn má jẹ ẹran tàbí kó má mu ọtí tàbí kó má ṣe ohunkóhun tó máa mú arákùnrin rẹ̀ kọsẹ̀.+