Mátíù 12:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Àwọn kan lára àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí wá fún un lésì pé: “Olùkọ́, a fẹ́ rí àmì kan látọ̀dọ̀ rẹ.”+ Lúùkù 11:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Nígbà tí àwọn èrò ń kóra jọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Ìran burúkú ni ìran yìí; ó ń wá àmì, àmọ́ a ò ní fún un ní àmì kankan àfi àmì Jónà.+
38 Àwọn kan lára àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí wá fún un lésì pé: “Olùkọ́, a fẹ́ rí àmì kan látọ̀dọ̀ rẹ.”+
29 Nígbà tí àwọn èrò ń kóra jọ, ó bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Ìran burúkú ni ìran yìí; ó ń wá àmì, àmọ́ a ò ní fún un ní àmì kankan àfi àmì Jónà.+