-
Fílípì 2:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 bí ẹ ṣe ń di ọ̀rọ̀ ìyè mú ṣinṣin.+ Nígbà náà, màá lè ní ìdí láti yọ̀ ní ọjọ́ Kristi, bí mo ṣe mọ̀ pé mi ò sáré lásán, mi ò sì ṣiṣẹ́ kára lásán.
-