ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 20:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ni Mósè bá gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ó sì fi ọ̀pá rẹ̀ lu àpáta náà lẹ́ẹ̀mejì, omi púpọ̀ wá ń tú jáde, àpéjọ náà àtàwọn ẹran ọ̀sìn wọn sì bẹ̀rẹ̀ sí í mu ún.+

  • Jòhánù 4:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Jésù dá a lóhùn pé: “Ká ní o mọ ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ Ọlọ́run+ ni, tí o sì mọ ẹni tó sọ fún ọ pé, ‘Fún mi lómi mu,’ ṣe lò bá bi í, ì bá sì ti fún ọ ní omi ìyè.”+

  • Jòhánù 4:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Obìnrin náà sọ fún un pé: “Mo mọ̀ pé Mèsáyà ń bọ̀, ẹni tí wọ́n ń pè ní Kristi. Nígbàkigbà tí ẹni yẹn bá dé, ó máa sọ gbogbo nǹkan fún wa ní gbangba.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́