-
Nọ́ńbà 21:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àwọn èèyàn náà wá ń sọ̀rọ̀ sí Ọlọ́run àti Mósè+ pé: “Kí ló dé tí ẹ kó wa kúrò ní Íjíbítì ká lè wá kú sínú aginjù? Kò sí oúnjẹ, kò sí omi,+ a* sì ti kórìíra oúnjẹ játijàti+ yìí.”* 6 Ni Jèhófà bá rán àwọn ejò olóró* sí àwọn èèyàn náà, wọ́n sì ń ṣán àwọn èèyàn náà débi pé ọ̀pọ̀ lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ló kú.+
-