ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 14:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nítorí bí o bá ṣẹ arákùnrin rẹ torí oúnjẹ, o ò rìn lọ́nà tó bá ìfẹ́ mu mọ́.+ Má fi oúnjẹ rẹ pa ẹni tí Kristi kú fún run.*+ 16 Nítorí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí wọ́n máa sọ̀rọ̀ nípa ohun rere tí ẹ̀ ń ṣe pé ibi ni.

  • 1 Kọ́ríńtì 8:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Tí ẹ bá ṣẹ àwọn arákùnrin yín lọ́nà yìí, tí ẹ sì kó bá ẹ̀rí ọkàn+ wọn tí kò lágbára, Kristi lẹ ṣẹ̀ sí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́