-
Kólósè 3:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ohunkóhun tí ẹ bá ń ṣe ní ọ̀rọ̀ tàbí ní ìṣe, ẹ máa ṣe ohun gbogbo ní orúkọ Jésù Olúwa, kí ẹ máa tipasẹ̀ rẹ̀ dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba.+
-