Róòmù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí kálukú wa máa ṣe ohun tó wu ọmọnìkejì rẹ̀ fún ire rẹ̀, láti gbé e ró.+ Fílípì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 bí ẹ ṣe ń wá ire àwọn ẹlòmíì,+ kì í ṣe tiyín nìkan.+