Jẹ́nẹ́sísì 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà Ọlọ́run wá sọ pé: “Kò dáa kí ọkùnrin náà máa dá wà. Màá ṣe olùrànlọ́wọ́ kan fún un, tó máa jẹ́ ẹnì kejì rẹ̀.”+
18 Jèhófà Ọlọ́run wá sọ pé: “Kò dáa kí ọkùnrin náà máa dá wà. Màá ṣe olùrànlọ́wọ́ kan fún un, tó máa jẹ́ ẹnì kejì rẹ̀.”+